Jer 4:16 YCE

16 Ẹ wi fun awọn orilẹ-ède; sa wò o, kede si Jerusalemu, pe, awọn ọluṣọ-ogun ti ilẹ jijin wá, nwọn si sọ ohùn wọn jade si ilu Juda.

Ka pipe ipin Jer 4

Wo Jer 4:16 ni o tọ