Jer 40:9 YCE

9 Gedaliah, ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, si bura fun wọn ati fun awọn ọkunrin wọn, wipe: Ẹ má bẹ̀ru lati sìn awọn ara Kaldea: ẹ gbe ilẹ̀ na, ki ẹ si mã sin ọba Babeli, yio si dara fun nyin.

Ka pipe ipin Jer 40

Wo Jer 40:9 ni o tọ