Jer 42:8 YCE

8 Nigbana ni o pè Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o wà pẹlu rẹ̀, ati gbogbo awọn enia lati ẹni-kekere titi de ẹni-nla.

Ka pipe ipin Jer 42

Wo Jer 42:8 ni o tọ