Jer 44:29 YCE

29 Eyi ni yio si jẹ àmi fun nyin, li Oluwa wi, pe, emi o jẹ nyin niya ni ibiyi, ki ẹnyin le mọ̀ pe: ọ̀rọ mi yio duro dajudaju si nyin fun ibi:

Ka pipe ipin Jer 44

Wo Jer 44:29 ni o tọ