Jer 46:12 YCE

12 Awọn orilẹ-ède ti gbọ́ itiju rẹ, igbe rẹ si ti kún ilẹ na: nitori alagbara ọkunrin ti kọsẹ lara alagbara, ati awọn mejeji si jumọ ṣubu pọ̀.

Ka pipe ipin Jer 46

Wo Jer 46:12 ni o tọ