Jer 47:6 YCE

6 Ye! iwọ idà Oluwa, yio ti pẹ to ki iwọ ki o to gbe jẹ? tẹ ara rẹ bọ inu akọ rẹ, simi! ki o si dakẹ!

Ka pipe ipin Jer 47

Wo Jer 47:6 ni o tọ