Jer 48:17 YCE

17 Gbogbo ẹnyin ti o wà yi i ka, ẹ kedaro rẹ̀; ati gbogbo ẹnyin ti o mọ̀ orukọ rẹ̀, ẹ wipe, bawo li ọpa agbara rẹ fi ṣẹ́, ọpa ogo!

Ka pipe ipin Jer 48

Wo Jer 48:17 ni o tọ