Jer 48:20 YCE

20 Oju tì Moabu: nitori a wó o lulẹ: ẹ hu, ki ẹ si kigbe; ẹ kede rẹ̀ ni Arnoni pe: a fi Moabu ṣe ijẹ,

Ka pipe ipin Jer 48

Wo Jer 48:20 ni o tọ