Jer 48:28 YCE

28 Ẹnyin olugbe Moabu! ẹ fi ilu wọnni silẹ, ki ẹ si mã gbe inu apata, ki ẹ si jẹ gẹgẹ bi oriri ti o kọ́ itẹ rẹ̀ li ẹba ẹnu ihò.

Ka pipe ipin Jer 48

Wo Jer 48:28 ni o tọ