Jer 51:20 YCE

20 Iwọ ni òlù mi, ohun elo-ogun: emi o fi ọ fọ awọn orilẹ-ède tũtu, emi o si fi ọ pa awọn ijọba run;

Ka pipe ipin Jer 51

Wo Jer 51:20 ni o tọ