Jer 6:22 YCE

22 Bayi li Oluwa wi, sa wò o, enia kan ti ilu ariwa wá, ati orilẹ-ède nla kan yio ti opin ilẹ aiye dide wá.

Ka pipe ipin Jer 6

Wo Jer 6:22 ni o tọ