Jer 7:21 YCE

21 Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi, kó ẹbọ sisun nyin pẹlu ẹbọ jijẹ nyin, ki ẹ si jẹ ẹran.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:21 ni o tọ