Jer 7:27 YCE

27 Bi iwọ ba si wi gbogbo ọ̀rọ wọnyi fun wọn, nwọn kì yio gbọ́ tirẹ: iwọ o si pè wọn, ṣugbọn nwọn kì o da ọ lohùn.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:27 ni o tọ