Jer 7:34 YCE

34 Emi o si mu ki ohùn inu-didun ki o da kuro ni ilu Juda ati kuro ni ita Jerusalemu, ohùn ayọ̀, ohùn ọkọ iyawo, ati ti iyawo; nitori ilẹ na yio di ahoro.

Ka pipe ipin Jer 7

Wo Jer 7:34 ni o tọ