11 Si lọ, tọ̀ awọn ti igbekùn lọ, awọn ọmọ enia rẹ, si ba wọn sọ̀rọ, ki o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; bi nwọn o gbọ́, tabi bi nwọn o kọ̀.
Ka pipe ipin Esek 3
Wo Esek 3:11 ni o tọ