Esek 3:10 YCE

10 Pẹlupẹlu o wi fun mi pe, Ọmọ enia, gba gbogbo ọ̀rọ ti emi o sọ fun ọ si ọkàn rẹ, si fi eti rẹ gbọ́ wọn.

Ka pipe ipin Esek 3

Wo Esek 3:10 ni o tọ