Esek 3:9 YCE

9 Bi okuta diamondi ti o le ju okuta ibọn ni mo ṣe iwaju rẹ: máṣe bẹ̀ru wọn, bẹ̃ni ki o máṣe fòya oju wọn, bi nwọn tilẹ jẹ ọlọ̀tẹ ile.

Ka pipe ipin Esek 3

Wo Esek 3:9 ni o tọ