Esek 44:4 YCE

4 O si mu mi wá ọ̀na ẹnu-ọ̀na ariwa siwaju ile na; mo si wò, si kiyesi i, ogo Oluwa kun ile Oluwa: mo si doju mi bolẹ.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:4 ni o tọ