Esek 7:18 YCE

18 Aṣọ ọ̀fọ ni nwọn o fi gbajá pẹlu; ìbẹru ikú yio si bò wọn mọlẹ; itiju yio si wà loju gbogbo wọn, ẽpá yio si wà li ori gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Esek 7

Wo Esek 7:18 ni o tọ