Jer 15:17 YCE

17 Emi kò joko ni ajọ awọn ẹlẹgan! ki emi si ni ayọ̀; mo joko emi nikan, nitori ọwọ rẹ: nitori iwọ ti fi ibanujẹ kún mi.

Ka pipe ipin Jer 15

Wo Jer 15:17 ni o tọ