Jer 15:18 YCE

18 Ẽṣe ti irora mi pẹ́ titi, ati ọgbẹ mi jẹ alaiwotan, ti o kọ̀ lati jina? lõtọ iwọ si dabi kanga ẹ̀tan fun mi, bi omi ti kò duro?

Ka pipe ipin Jer 15

Wo Jer 15:18 ni o tọ