Jer 17:10 YCE

10 Emi, Oluwa, ni iwá awari ọkàn enia, emi ni ndan inu wò, ani lati fi fun olukuluku gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀, ati gẹgẹ bi eso iṣe rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:10 ni o tọ