Jer 17:19 YCE

19 Bayi li Oluwa wi fun mi; Lọ, ki o si duro ni ẹnu-ọ̀na awọn enia nibi ti awọn ọba Juda nwọle, ti nwọn si njade, ati ni gbogbo ẹnu-bode Jerusalemu.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:19 ni o tọ