Jer 17:20 YCE

20 Ki o si wi fun wọn pe, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa, ẹnyin ọba Juda ati gbogbo Juda, ati gbogbo ẹnyin olugbe Jerusalemu, ti o nkọja ninu ẹnu-bode wọnyi.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:20 ni o tọ