Jer 19:6 YCE

6 Nitorina, sa wò o, ọjọ mbọ̀, li Oluwa wi, a kì yio pe orukọ ibi yi ni Tofeti mọ, tabi afonifoji ọmọ Hinnomu, ṣugbọn Afonifoji ipakupa.

Ka pipe ipin Jer 19

Wo Jer 19:6 ni o tọ