Jer 24:9 YCE

9 Emi o fi wọn fun iwọsi ati fun ibi ninu gbogbo ijọba aiye, lati di ìtiju, owe, ẹsin, ati ẹ̀gan ni ibi gbogbo, ti emi o le wọn si.

Ka pipe ipin Jer 24

Wo Jer 24:9 ni o tọ