Jer 28:8 YCE

8 Awọn woli ti o ti ṣaju mi, ati ṣaju rẹ ni igbãni sọ asọtẹlẹ pupọ, ati si ijọba nla niti ogun, ati ibi, ati ajakalẹ-arun.

Ka pipe ipin Jer 28

Wo Jer 28:8 ni o tọ