Jer 4:27 YCE

27 Nitori bayi li Oluwa wi pe: Gbogbo ilẹ ni yio di ahoro; ṣugbọn emi kì yio ṣe ipari tan.

Ka pipe ipin Jer 4

Wo Jer 4:27 ni o tọ