Jer 4:3 YCE

3 Nitori bayi li Oluwa wi fun awọn ọkunrin Juda, ati Jerusalemu pe, tú ilẹ titun fun ara nyin, ki ẹ má si gbìn lãrin ẹ̀gun.

Ka pipe ipin Jer 4

Wo Jer 4:3 ni o tọ