Jer 41:11 YCE

11 Ṣugbọn nigbati Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o pẹlu rẹ̀, gbọ́ ibi ti Iṣmaeli, ọmọ Netaniah ti ṣe,

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:11 ni o tọ