Jer 41:12 YCE

12 Nigbana ni nwọn kó gbogbo awọn ọkunrin, nwọn si lọ iba Iṣmaeli, ọmọ Netaniah jà, nwọn si ri i li ẹba omi nla ti o wà ni Gibeoni.

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:12 ni o tọ