Jer 41:13 YCE

13 O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia ti o wà pẹlu Iṣmaeli ri Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o pẹlu rẹ̀, nwọn si yọ̀,

Ka pipe ipin Jer 41

Wo Jer 41:13 ni o tọ