Jer 9:15 YCE

15 Nitorina bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi; sa wò o, awọn enia yi pãpa ni emi o fi wahala bọ́, emi o si mu wọn mu omi orõro.

Ka pipe ipin Jer 9

Wo Jer 9:15 ni o tọ