Aisaya 1:14 BM

14 Ninu ọkàn mi, mo kórìíra àwọn àjọ̀dún oṣù tuntun yín, ati àwọn àjọ̀dún pataki yín.Wọ́n ti di ẹrù wúwo fún mi,n kò lè gbé e mọ́, ó sú mi.

Ka pipe ipin Aisaya 1

Wo Aisaya 1:14 ni o tọ