Aisaya 1:7 BM

7 Orílẹ̀-èdè yín ti di ahoro,wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín.Àwọn àjèjì sì ti jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.Ó di ahoro bí èyí tí àwọn àjèjì wó palẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 1

Wo Aisaya 1:7 ni o tọ