Aisaya 10:25 BM

25 Nítorí pé láìpẹ́, ibinu mi si yín yóo kásẹ̀ nílẹ̀, n óo sì dojú ibinu mi kọ wọ́n láti pa wọ́n run.

Ka pipe ipin Aisaya 10

Wo Aisaya 10:25 ni o tọ