Aisaya 11:12 BM

12 Yóo gbé àsíá sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè,yóo kó àwọn Israẹli tí a ti patì jọ.Yóo ṣa àwọn ọmọ Juda tí wọ́n fọ́nká jọ,láti orígun mẹrẹẹrin ilẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:12 ni o tọ