Aisaya 11:14 BM

14 Wọn óo kọlu àwọn ará Filistini ní ìhà ìwọ̀ oòrùn,wọn yóo jọ ṣẹgun àwọn ará ìlà oòrùn.Wọn yóo sì jọ dojú ìjà kọ Edomu ati Moabu.Àwọn ará Amoni yóo gbọ́ràn sí wọn lẹ́nu.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:14 ni o tọ