Aisaya 11:9 BM

9 Wọn kò ní ṣe eniyan ní jamba mọ́,tabi kí wọ́n bu eniyan jẹ ní gbogbo orí òkè mímọ́ mi.Nítorí ìmọ̀ OLUWA yóo kún gbogbo ayébí omi ṣe kún gbogbo inú òkun.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:9 ni o tọ