6 Ẹ̀yin tí ń gbé Sioni,ẹ hó, ẹ kọrin ayọ̀, ẹ̀yin olùgbé Sioni,nítorí Ẹni ńlá ni Ẹni Mímọ́ Israẹlití ó wà láàrin yín.”
Ka pipe ipin Aisaya 12
Wo Aisaya 12:6 ni o tọ