10 Nítorí àgbájọpọ̀ àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀runyóo kọ̀, wọn kò ní tan ìmọ́lẹ̀.Oòrùn yóo ṣókùnkùn nígbà tí ó bá yọ,òṣùpá kò sì ní tan ìmọ́lẹ̀.
Ka pipe ipin Aisaya 13
Wo Aisaya 13:10 ni o tọ