Aisaya 13:19 BM

19 Babiloni, ìwọ tí o lógo jù láàrin gbogbo ìjọba ayé,ìwọ tí o jẹ́ ẹwà ati ògo àwọn ará Kalidea,yóo dàbí Sodomu ati Gomora,nígbà tí Ọlọrun pa wọ́n run.

Ka pipe ipin Aisaya 13

Wo Aisaya 13:19 ni o tọ