Aisaya 13:5 BM

5 Wọ́n wá láti ilẹ̀ òkèèrè,láti ìpẹ̀kun ayé.OLUWA ń bọ̀ pẹlu àwọn ohun ìjà ibinu rẹ̀,tí yóo fi pa gbogbo ayé run.

Ka pipe ipin Aisaya 13

Wo Aisaya 13:5 ni o tọ