Aisaya 14:32 BM

32 Èsì wo ni a óo fún àwọn ikọ̀ orílẹ̀-èdè Filistini?A óo sọ fún wọn pé,“OLUWA ti fi ìdí Sioni sọlẹ̀àwọn tí à ń pọ́n lójú láàrin àwọn eniyan rẹ̀yóo fi ibẹ̀ ṣe ibi ààbò.”

Ka pipe ipin Aisaya 14

Wo Aisaya 14:32 ni o tọ