Aisaya 17:7 BM

7 Tó bá di ìgbà náà, àwọn eniyan yóo bọ̀wọ̀ fún Ẹlẹ́dàá wọn, wọn yóo sì máa wo ojú Ẹni Mímọ́ Israẹli.

Ka pipe ipin Aisaya 17

Wo Aisaya 17:7 ni o tọ