Aisaya 19:1 BM

1 Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Ijipti nìyí:OLUWA gun ìkùukùu lẹ́ṣin, ó ń yára bọ̀ wá sí Ijipti.Àwọn oriṣa Ijipti yóo máa gbọ̀n níwájú rẹ̀,ọkàn àwọn ará Ijipti yóo sì dàrú.

Ka pipe ipin Aisaya 19

Wo Aisaya 19:1 ni o tọ