Aisaya 19:22 BM

22 OLUWA yóo fìyà jẹ àwọn ará Ijipti ṣugbọn yóo wò wọ́n sàn, wọn yóo pada sọ́dọ̀ OLUWA, yóo gbọ́ adura wọn, yóo sì wò wọ́n sàn.

Ka pipe ipin Aisaya 19

Wo Aisaya 19:22 ni o tọ