Aisaya 2:12 BM

12 Nítorí OLUWA àwọn ọmọ ogun ti ya ọjọ́ kan sọ́tọ̀,tí yóo dojú ìjà kọ àwọn agbéraga,ati àwọn ọlọ́kàn gíga,ati gbogbo nǹkan tí à ń gbéga.

Ka pipe ipin Aisaya 2

Wo Aisaya 2:12 ni o tọ