Aisaya 2:21 BM

21 Wọn óo wọ inú pàlàpálá àpáta,ati inú ihò àwọn òkè gíga;nígbà tí wọn bá ń sá fún ibinu OLUWA,ati ògo ọlá ńlá rẹ̀,nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.

Ka pipe ipin Aisaya 2

Wo Aisaya 2:21 ni o tọ