Aisaya 20:5 BM

5 Ìbẹ̀rù-bojo yóo dé ba yín, ojú yóo sì tì yín; nítorí Kuṣi ati Ijipti tí ẹ gbójú lé.

Ka pipe ipin Aisaya 20

Wo Aisaya 20:5 ni o tọ